Quantcast
Channel: Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 10442

Ifa ni…Mariwo fi’bi faara la ile;

$
0
0

Mariwo fi’bi faara la ile;
Awo won ni Ile Ìlalà;
A difa fun won ni Ile Ìlalà;
Nibi ojumo rere tii mo ni;
Ojumo rere lo mo wa loni o.
Aase!
Ifa says:
Mariwo fi’bi faara la ile;
The Awo of the town of Ìlalà;
Cast Ifa for them in the town of Ìlalà;
Where they wake up daily with Ire gbogbo;
It is ojumo’re to us today!
Aase!

 

 

‎IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole‎


Viewing all articles
Browse latest Browse all 10442

Trending Articles