Quantcast
Channel: Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 10442

Isu Oro bale ro pee…

$
0
0

A da fun eji, ti o ma bowo fun iko Odidere,
won ni ko kara nile, Ebo ni ko mu se.
Ojo o ni ro ko pa ina iko Odidere,
Iko Odidere d’Orisa.
Ni Agbara Olodumare ati oruko Orunmila,
Gbogbo ilara, ote, egan, ikorira, ati tembelekun awon ajogun ati elenini aye; Ko ni pa’na Ayo ati Ogo aye gbogbo wa.
Ire ati Alaafia fun gbogbo wa.
Aboru Aboye o


Viewing all articles
Browse latest Browse all 10442

Trending Articles