Quantcast
Channel: Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 10442

Awon eniyan ti bere si ni fi adura ranse si oga @DeleMomodu

$
0
0

@DeleMomodu, okan ninu awon oga oniroyin ile Naijeria, eni ti pupo ninu awon akegbe re feran lati maa pe ni Bob Dee, ni okan ninu oju meji re n yo lenu bayii.

Won ti se ise abe fun adari ati alakoso magasininni Ovation to kari aye, ise abe naa si kesejari.

Adura wa ni wi pe ki Oba oke tun bo fun okunrin naa ni alaafia to peye si i. Amin

E wo adura awon eniyan ti won fe Dele Momodu nibi:

The post Awon eniyan ti bere si ni fi adura ranse si oga @DeleMomodu appeared first on Ọmọ Oódua.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 10442

Trending Articles