Quantcast
Channel: Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 10442

Dayo Amusa ti pada senu ise

$
0
0

Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi won ti n dana fiimu tuntun.

The post Dayo Amusa ti pada senu ise appeared first on Ọmọ Oódua.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 10442

Trending Articles