Quantcast
Channel: Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 10442

Maheeda di Pasito oloro itunnu

$
0
0

Kosi eni ti Olorun ko le fi owo to lokan. Maheeda, okan ninu awon olorin ile Naijiria, ti ma n bora sile nihoho tele ti wa di eni ti n gba awon eniyan niyanju bayii pelu oro itunnu ti n mu inu awon ololufe re dun.

The post Maheeda di Pasito oloro itunnu appeared first on Ọmọ Oódua.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 10442

Trending Articles