Aare Muhammadu Buhari ti bale ni Tehran to wa ni orileede Iran nibi ti yoo ti maa joko se ipade eleeketa iru e ti egbe awon orileede ti n gbe epo robi jade fun awon orileede agbaye.
The post Baalu Aare Buhar ti bale niluu Iran appeared first on Ọmọ Oódua.