Titi aye ni olowo yoo ma sore olowo. Gbajumo yoo ma sore gbajumo nigba ti awon olosi naa yoo ma ba ara won se ninu asosiesan awon mekunnu. Aisha Buhari, aya aare ile Naijiria ti lo ki Oloye agba egbe APC, Bola Ahmed Tinubu ninu aafin re.
The post Iyawo Buhari lo ki Tinubu laafin re appeared first on Ọmọ Oódua.